Jeremaya 32:39 BM

39 N óo fún wọn ní ọkàn ati ẹ̀mí kan, kí wọn lè máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo, kí ó lè dára fún àwọn ati àwọn ọmọ wọn lẹ́yìn wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:39 ni o tọ