Jeremaya 34:7 BM

7 ní àkókò tí àwọn ọmọ ogun ọba Babiloni gbógun ti Jerusalẹmu ati Lakiṣi ati Aseka, nítorí pé àwọn nìkan ni wọ́n ṣẹ́kù ninu àwọn ìlú olódi Juda.

Ka pipe ipin Jeremaya 34

Wo Jeremaya 34:7 ni o tọ