Jeremaya 35:16 BM

16 Àwọn ọmọ Jonadabu, ọmọ Rekabu mú àṣẹ baba ńlá wọn tí ó pa fún wọn ṣẹ, ṣugbọn àwọn eniyan wọnyi kò gbọ́ràn sí mi lẹ́nu.

Ka pipe ipin Jeremaya 35

Wo Jeremaya 35:16 ni o tọ