Jeremaya 35:19 BM

19 nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní títí lae, kò ní sí ìgbà kan tí Jonadabu, ọmọ Rekabu kò ní ní ẹnìkan tí yóo máa ṣe iṣẹ́ ìsìn níwájú mi.’ ”

Ka pipe ipin Jeremaya 35

Wo Jeremaya 35:19 ni o tọ