Jeremaya 35:3 BM

3 Mo bá mú Jaasanaya ọmọ Jeremaya ọmọ Habasinaya ati àwọn arakunrin rẹ̀ ati gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ ati gbogbo ìdílé Rekabu,

Ka pipe ipin Jeremaya 35

Wo Jeremaya 35:3 ni o tọ