Jeremaya 36:24 BM

24 Sibẹ ẹ̀rù kò ba ọba tabi àwọn iranṣẹ rẹ̀ tí wọ́n gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí, wọn kò sì fa aṣọ wọn ya.

Ka pipe ipin Jeremaya 36

Wo Jeremaya 36:24 ni o tọ