Jeremaya 37:3 BM

3 Ọba Sedekaya rán Jehukali, ọmọ Ṣelemaya, ati Sefanaya, alufaa, ọmọ Maaseaya, sí Jeremaya wolii, pé kí ó jọ̀wọ́ bá àwọn gba adura sí OLUWA Ọlọrun.

Ka pipe ipin Jeremaya 37

Wo Jeremaya 37:3 ni o tọ