Jeremaya 38:10 BM

10 Ọba bá pàṣẹ fún Ebedimeleki ará Etiopia, ó ní, “Mú eniyan mẹta lọ́wọ́, kí ẹ lọ yọ Jeremaya wolii kúrò ninu kànga náà kí ó tó kú.”

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:10 ni o tọ