Jeremaya 38:13 BM

13 Wọ́n bá fi okùn fa Jeremaya jáde kúrò ninu kànga. Jeremaya bá ń gbé gbọ̀ngàn àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin.

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:13 ni o tọ