Jeremaya 38:24 BM

24 Sedekaya ọba bá kìlọ̀ fún Jeremaya pé, “Má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ gbogbo nǹkan tí a jọ sọ, o kò sì ní kú.

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:24 ni o tọ