Jeremaya 39:1 BM

1 Ní oṣù kẹwaa, ọdún kẹsan-an ìjọba Sedekaya, ọba Juda, Nebukadinesari, ọba Babiloni, ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dótì í.

Ka pipe ipin Jeremaya 39

Wo Jeremaya 39:1 ni o tọ