Jeremaya 43:4 BM

4 Nítorí náà Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo àwọn olórí ogun ati gbogbo àwọn ará ìlú kò gba ohun tí OLUWA sọ, pé kí wọ́n dúró ní ilẹ̀ Juda.

Ka pipe ipin Jeremaya 43

Wo Jeremaya 43:4 ni o tọ