Jeremaya 48:26 BM

26 OLUWA ní,“Ẹ rọ Moabu lọ́tí yó,nítorí pé ó gbéraga sí OLUWA;kí ó lè máa yíràá ninu èébì rẹ̀,a óo sì fi òun náà ṣẹ̀sín.

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:26 ni o tọ