Jeremaya 48:31 BM

31 Nítorí náà, ni mo ṣe ń sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, tí mò ń kígbe sókè nítorí Moabutí mo sì ń ṣọ̀fọ̀ nítorí àwọn ará Kiri Heresi.

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:31 ni o tọ