Jeremaya 50:20 BM

20 OLUWA ní, Nígbà tí ó bá yá, tí àkókò bá tó, a óo wá ẹ̀ṣẹ̀ tì ní Israẹli ati Juda; nítorí pé n óo dáríjì àwọn tí mo bá ṣẹ́kù.”

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:20 ni o tọ