Jeremaya 50:27 BM

27 Ẹ pa gbogbo akọ mààlúù rẹ̀,ẹ fà wọ́n lọ sí ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran.Àwọn ará Babiloni gbé, nítorí ọjọ́ wọn ti pé,àní ọjọ́ ìjìyà wọn.”

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:27 ni o tọ