Jeremaya 50:31 BM

31 “Wò ó! Mo dojú kọ ọ́,ìwọ onigbeeraga yìí,nítorí pé ọjọ́ ti pé tí n óo jẹ ọ́ níyà.Èmi OLUWA, Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:31 ni o tọ