Jeremaya 50:38 BM

38 Ọ̀dá yóo dá ní ilẹ̀ wọn,kí àwọn odò wọn lè gbẹ!Nítorí pé ilẹ̀ tí ó kún fún ère ni,wọ́n sì kúndùn ìbọ̀rìṣà.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:38 ni o tọ