Jeremaya 51:25 BM

25 Wò ó! Mo lòdì sí ọ, ìwọ òkè ìparun,tí ò ń pa gbogbo ayé run.N óo gbá ọ mú, n óo tì ọ́ lulẹ̀ láti orí àpáta,n óo sì sọ ọ́ di òkè tí ó jóná.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:25 ni o tọ