35 Jẹ́ kí àwọn tí ń gbé Sioni wí pé,‘Kí ibi tí àwọn ará Babiloni ṣe sí wa ati sí àwọn arakunrin wa dà lé wọn lórí.’Kí àwọn ará Jerusalẹmu sì wí pé,‘Ẹ̀jẹ̀ wa ń bẹ lórí àwọn ará ilẹ̀ Kalidea.’ ”
Ka pipe ipin Jeremaya 51
Wo Jeremaya 51:35 ni o tọ