64 kí ó sì sọ wí pé, “Báyìí ni yóo rí fún Babiloni, kò sì ní gbérí mọ́, nítorí ibi tí OLUWA yóo mú kí ó dé bá a.”Ibí yìí ni àwọn ọ̀rọ̀ tí Jeremaya sọ parí sí.
Ka pipe ipin Jeremaya 51
Wo Jeremaya 51:64 ni o tọ