13 OLUWA ní, “Láti orí àwọn mẹ̀kúnnù títí dé orí àwọn eniyan pataki pataki,gbogbo wọn ni wọ́n fẹ́ràn èrè àjẹjù;láti orí àwọn wolii títí dé orí àwọn alufaa,èké ni gbogbo wọn.
Ka pipe ipin Jeremaya 6
Wo Jeremaya 6:13 ni o tọ