Jeremaya 6:17 BM

17 Mo fi àwọn aṣọ́nà ṣọ́nà nítorí yín.Mo wí fún wọn pé,“Ẹ máa dẹtí sílẹ̀ sí fèrè ogun!”Ṣugbọn wọ́n ní, “A kò ní dẹtí sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:17 ni o tọ