Jeremaya 6:19 BM

19 Gbọ́! Ìwọ ilẹ̀;n óo fa ibi lé àwọn eniyan wọnyi lórí,wọn óo jèrè èso ìwà burúkú wọn;nítorí pé wọn kò fetí sí ọ̀rọ̀ mi,wọ́n sì ti tàpá sí òfin mi.

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:19 ni o tọ