Jeremaya 6:21 BM

21 Nítorí náà, n óo gbé ohun ìdínà sọ́nà fún àwọn eniyan wọnyi,wọn óo sì fẹsẹ̀ kọ;ati baba, àtọmọ wọn,àtaládùúgbò, àtọ̀rẹ́,gbogbo wọn ni yóo parun.”

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:21 ni o tọ