25 Ẹ má lọ sinu oko,ẹ má sì ṣe rìn lójú ọ̀nà náà,nítorí ọ̀tá mú idà lọ́wọ́,ìdágìrì sì wà káàkiri.
Ka pipe ipin Jeremaya 6
Wo Jeremaya 6:25 ni o tọ