Jeremaya 6:27 BM

27 Mo ti fi ọ́ ṣe ẹni tí yóo máa dán àwọn eniyan mi wò,o óo máa dán wọn wò bí ẹni dán irin wò,o óo gbìyànjú láti mọ ọ̀nà wọn,kí o lè yẹ ọ̀nà wọn wò, kí o sì mọ̀ ọ́n.

Ka pipe ipin Jeremaya 6

Wo Jeremaya 6:27 ni o tọ