Jeremaya 7:20 BM

20 Nítorí náà, èmi OLUWA Ọlọrun óo tú ibinu gbígbóná mi sórí ibí yìí, n óo bínú sí eniyan ati ẹranko, ati igi oko ati èso ilẹ̀. Ibinu mi óo jó wọn run bí iná, kò sì ní ṣe é pa.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:20 ni o tọ