Jeremaya 7:22 BM

22 Nítorí ní ọjọ́ tí mo kó àwọn baba yín jáde ní ilẹ̀ Ijipti, n kò bá wọn sọ̀rọ̀ ẹbọ sísun tabi ẹbọ rírú, bẹ́ẹ̀ ni n kò pàṣẹ rẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:22 ni o tọ