Jeremaya 7:3 BM

3 OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní: ‘Ẹ tún ìrìn ẹsẹ̀ yín ati iṣẹ́ ọwọ́ yín ṣe, kí n lè jẹ́ kí ẹ máa gbé ìhín.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:3 ni o tọ