Jeremaya 7:30 BM

30 “Àwọn ọmọ Juda ti ṣe nǹkan burúkú. Wọ́n gbé ère wọn kalẹ̀ ninu ilé tí à ń fi orúkọ mi pè, wọ́n sì ti sọ ọ́ di aláìmọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 7

Wo Jeremaya 7:30 ni o tọ