Jeremaya 9:15 BM

15 Nítorí náà, n óo fún wọn ní igi tí ó korò jẹ, n óo sì fún wọn ní omi tí ó ní májèlé mu. Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:15 ni o tọ