Jeremaya 9:7 BM

7 Nítorí náà, ó ní:“Wò ó! N óo fọ̀ wọ́n mọ́,n óo dán wọn wò.Àbí, kí ni kí n tún ṣe fún àwọn eniyan yìí?

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:7 ni o tọ