Jeremaya 9:9 BM

9 Ṣé n kò wá ní jẹ wọ́n níyà fún àwọn nǹkan tí wọ́n ṣe wọnyi?Àbí n kò ní gbẹ̀san ara mi lára irú orílẹ̀-èdè yìí?”

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:9 ni o tọ