Jeremaya 16:14 BM

14 Nítorí náà, OLUWA ní, “Àkókò ń bọ̀, tí wọn kò ní máa búra mọ́ pé, ‘Bí OLUWA, tí ó kó àwọn ọmọ Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti tí ń bẹ,’

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:14 ni o tọ