15 Ègún ni fún ẹni tí ó yọ̀ fún baba mi,tí ó sọ fún un pé,“Iyawo rẹ ti bí ọmọkunrin kan fún ọ,tí ó mú inú rẹ̀ dùn.”
Ka pipe ipin Jeremaya 20
Wo Jeremaya 20:15 ni o tọ