Jeremaya 27:20 BM

20 tí Nebukadinesari, ọba Babiloni, kò kó lọ, nígbà tí ó kó Jehoiakini, ọba Juda, ọmọ Jehoiakimu, ati gbogbo àwọn ọlọ́lá Juda ati ti Jerusalẹmu lọ sí Babiloni.

Ka pipe ipin Jeremaya 27

Wo Jeremaya 27:20 ni o tọ