Jeremaya 27:19 BM

19 Àwọn ohun èlò kan ṣẹ́kù ninu ilé OLUWA, àwọn bíi: òpó ilé, ati agbada omi tí a fi idẹ ṣe, ati àwọn ìtẹ́lẹ̀ rẹ̀ ati àwọn ohun èlò tí ó kù ninu ìlú yìí,

Ka pipe ipin Jeremaya 27

Wo Jeremaya 27:19 ni o tọ