Jeremaya 28:15 BM

15 Jeremaya wolii bá sọ fún Hananaya pé, “Tẹ́tí sílẹ̀, Hananaya, OLUWA kò rán ọ níṣẹ́, o sì ń jẹ́ kí àwọn eniyan wọnyi gbẹ́kẹ̀lé irọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 28

Wo Jeremaya 28:15 ni o tọ