Jeremaya 28:16 BM

16 Nítorí náà, OLUWA ní: òun óo mú ọ kúrò lórí ilẹ̀ ayé. Ní ọdún yìí gan-an ni o óo sì kú, nítorí pé o ti sọ ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀ sí OLUWA.”

Ka pipe ipin Jeremaya 28

Wo Jeremaya 28:16 ni o tọ