Jeremaya 3:23 BM

23 Nítòótọ́, ẹ̀tàn ni àwọn òkè,ati gbogbo ohun tí wọn ń lọ ṣe níbẹ̀;dájúdájú lọ́dọ̀ OLUWA Ọlọrun wa ni ìgbàlà Israẹli wà.

Ka pipe ipin Jeremaya 3

Wo Jeremaya 3:23 ni o tọ