Jeremaya 3:24 BM

24 Ṣugbọn láti ìgbà èwe wa ni ohun ìtìjú yìíti pa gbogbo ohun tí àwọn baba ńlá wa ṣiṣẹ́ fún run:ẹran ọ̀sìn wọn, ati agbo mààlúù wọn,àwọn ọmọ wọn lọkunrin ati lobinrin.

Ka pipe ipin Jeremaya 3

Wo Jeremaya 3:24 ni o tọ