Jeremaya 4:6 BM

6 Ẹ gbé àsíá sókè sí Sioni,pé kí wọn sá àsálà, kí wọn má ṣe dúró,nítorí mò ń mú ibi ati ìparun ńlá bọ̀ láti ìhà àríwá.

Ka pipe ipin Jeremaya 4

Wo Jeremaya 4:6 ni o tọ