14 Ni gbogbo àwọn tí Iṣimaeli kó lẹ́rú ní Misipa bá yipada kúrò lẹ́yìn rẹ̀, wọ́n lọ bá Johanani ọmọ Karea.
Ka pipe ipin Jeremaya 41
Wo Jeremaya 41:14 ni o tọ