15 Ṣugbọn Iṣimaeli, ọmọ Netanaya, pẹlu àwọn mẹjọ sá àsálà lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Amoni.
Ka pipe ipin Jeremaya 41
Wo Jeremaya 41:15 ni o tọ