Jeremaya 48:5 BM

5 Bí wọn tí ń gun òkè Luhiti, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń sọkún,nítorí pé nígbà tí wọn tí ń lọ níbi ẹsẹ̀ òkè Horonaimu,ni wọ́n tí ń gbọ́ igbe ìparun; pé,

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:5 ni o tọ