Jeremaya 50:17 BM

17 OLUWA ní, “Israẹli dàbí aguntan tí àwọn kinniun ń lé kiri. Ọba Asiria ni ó kọ́kọ́ fi ṣe ẹran ìjẹ, ọba Babiloni sì ń wó àwọn egungun rẹ̀ tí ó kù.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:17 ni o tọ