Jeremaya 50:18 BM

18 Nítorí náà èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli, ni mo sọ pé n óo jẹ ọba Babiloni ati ilẹ̀ rẹ̀ níyà, bí mo ṣe jẹ ọba Asiria níyà.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:18 ni o tọ