Jeremaya 50:35 BM

35 OLUWA ní,“Idà ni yóo pa àwọn ará Kalidea,idà ni yóo pa àwọn ará Babiloni,ati àwọn ìjòyè wọn,ati àwọn amòye wọn!

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:35 ni o tọ