Jeremaya 50:36 BM

36 Idà ni yóo pa àwọn awoṣẹ́ wọn,kí wọ́n lè di òpè!Idà ni yóo pa àwọn ọmọ ogun wọn,kí wọ́n lè parẹ́!

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:36 ni o tọ